Samuẹli Keji 14:20 BM

20 Ṣugbọn, òun náà fẹ́ tún nǹkan ṣe, ni ó fi ṣe ohun tí ó ṣe. Ṣugbọn kabiyesi ní ọgbọ́n bí angẹli Ọlọ́run, láti mọ ohun gbogbo lórí ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 14

Wo Samuẹli Keji 14:20 ni o tọ