Samuẹli Keji 15:17 BM

17 Bí ọba ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ ti ń jáde kúrò ní ìlú, wọ́n dúró níbi ilé tí ó wà ní ìpẹ̀kun ìlú.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:17 ni o tọ