Samuẹli Keji 15:25 BM

25 Ọba wí fún Sadoku pé, “Gbé Àpótí Ẹ̀rí náà pada sí ìlú. Bí inú OLUWA bá dùn sí mi, bí mo bá bá ojurere OLUWA pàdé, yóo mú mi pada, n óo tún fi ojú kan Àpótí Ẹ̀rí náà ati ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 15

Wo Samuẹli Keji 15:25 ni o tọ