Samuẹli Keji 16:15 BM

15 Absalomu ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ wọ Jerusalẹmu lọ, Ahitofeli sì wà pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 16

Wo Samuẹli Keji 16:15 ni o tọ