Samuẹli Keji 16:17 BM

17 Absalomu bá bi í pé, “Kí ló dé, tí o kò fi ṣe olótìítọ́ sí Dafidi ọ̀rẹ́ rẹ mọ́? Kí ló dé tí o kò fi bá a lọ?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 16

Wo Samuẹli Keji 16:17 ni o tọ