Samuẹli Keji 17:12 BM

12 A óo kọlu Dafidi níbikíbi tí a bá ti bá a, a óo bò wọ́n bí ìgbà tí ìrì bá sẹ̀ sórí ilẹ̀; ẹnikẹ́ni kò sì ní yè ninu òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:12 ni o tọ