Samuẹli Keji 17:15 BM

15 Huṣai bá lọ sọ fún Sadoku ati Abiatari, àwọn alufaa mejeeji, irú ìmọ̀ràn tí Ahitofeli fún Absalomu ati àwọn ọmọ Israẹli, ati èyí tí òun fún wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:15 ni o tọ