Samuẹli Keji 17:22 BM

22 Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí rékọjá sí òdìkejì odò Jọdani. Nígbà tí ilẹ̀ yóo fi mọ́, gbogbo wọn ti kọjá tán.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:22 ni o tọ