Samuẹli Keji 17:3 BM

3 N óo sì kó gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ, gẹ́gẹ́ bí iyawo tí ó lọ bá ọkọ rẹ̀ nílé. Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ni o fẹ́ pa, àwọn eniyan yòókù yóo sì wà ní alaafia.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 17

Wo Samuẹli Keji 17:3 ni o tọ