Samuẹli Keji 18:10 BM

10 Ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ogun Dafidi rí i, ó bá lọ sọ fún Joabu pé òun rí Absalomu tí ó ń rọ̀ lórí igi Oaku.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:10 ni o tọ