Samuẹli Keji 18:15 BM

15 Mẹ́wàá ninu àwọn ọdọmọkunrin tí wọn ń ru ihamọra Joabu bá yí Absalomu po, wọ́n sì ṣá a pa.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:15 ni o tọ