Samuẹli Keji 18:17 BM

17 Wọ́n gbé òkú Absalomu jù sinu ihò jíjìn kan ninu igbó, wọ́n sì kó ọpọlọpọ òkúta jọ sórí òkú rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọ ogun Israẹli bá sá, olukuluku gba ilé rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:17 ni o tọ