Samuẹli Keji 18:19 BM

19 Ahimaasi, ọmọ Sadoku bá sọ fún Joabu pé, “Jẹ́ kí n sáré tọ ọba lọ, kí n sì fún un ní ìròyìn ayọ̀ náà, pé OLUWA ti gbà á lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:19 ni o tọ