6 Àwọn ọmọ ogun náà bá jáde lọ sinu pápá láti bá àwọn ọmọ ogun Israẹli jà, ní aṣálẹ̀ Efuraimu.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18
Wo Samuẹli Keji 18:6 ni o tọ