Samuẹli Keji 19:15 BM

15 Nígbà tí ọba ń pada bọ̀, àwọn eniyan Juda wá sí Giligali láti pàdé rẹ̀ ati láti mú un kọjá odò Jọdani.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:15 ni o tọ