Samuẹli Keji 19:27 BM

27 Ó lọ pa irọ́ mọ́ mi lọ́dọ̀ ọba. Ṣugbọn bí angẹli Ọlọrun ni oluwa mi, ọba rí; nítorí náà, ṣe ohun tí ó bá tọ́ sí mi ní ojú rẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:27 ni o tọ