Samuẹli Keji 19:30 BM

30 Mẹfiboṣẹti bá dáhùn pé, “Jẹ́ kí Siba máa mú gbogbo rẹ̀, kìkì pé kabiyesi pada dé ilé ní alaafia ti tó fún mi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:30 ni o tọ