Samuẹli Keji 19:36 BM

36 Irú anfaani ńlá báyìí kò tọ́ sí mi láti ọ̀dọ̀ ọba, nítorí náà, n óo bá ọba gun òkè odò Jọdani, n óo sì bá ọ lọ sí iwájú díẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:36 ni o tọ