Samuẹli Keji 19:39 BM

39 Lẹ́yìn náà ni Dafidi ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ gòkè odò Jọdani. Ó kí Basilai, ó fi ẹnu kò ó ní ẹnu, ó sì súre fún un; Basilai bá pada sí ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 19

Wo Samuẹli Keji 19:39 ni o tọ