Samuẹli Keji 2:10 BM

10 Ẹni ogoji ọdún ni nígbà tí wọ́n fi jọba lórí Israẹli, ó sì wà lórí oyè fún ọdún meji.Ṣugbọn ẹ̀yìn Dafidi ni gbogbo ẹ̀yà Juda wà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:10 ni o tọ