Samuẹli Keji 2:12 BM

12 Abineri ọmọ Neri ati àwọn iranṣẹ Iṣiboṣẹti, ọmọ Saulu, ṣígun láti Mahanaimu, lọ sí ìlú Gibeoni.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:12 ni o tọ