Samuẹli Keji 2:25 BM

25 Àwọn ọmọ ogun yòókù láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini kó ara wọn jọ sẹ́yìn Abineri, wọ́n sì dúró káàkiri lórí òkè, pẹlu ìmúra ogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:25 ni o tọ