Samuẹli Keji 2:6 BM

6 Kí OLUWA fi ìfẹ́ ńlá ati òdodo rẹ̀ hàn fun yín. Èmi náà yóo ṣe yín dáradára, nítorí ohun tí ẹ ṣe yìí.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:6 ni o tọ