Samuẹli Keji 20:1 BM

1 Aláìníláárí ẹ̀dá kan wà ní ààrin àwọn ará Giligali tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ṣeba, ọmọ Bikiri, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini. Ọkunrin yìí fọn fèrè, ó ní,“Kò sí ohun tí ó kàn wá pẹlu Dafidi,a kò sì ní ìpín nílé ọmọ Jese.Ẹ pada sí ilé yín, ẹ̀yin ọmọ Israẹli.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:1 ni o tọ