Samuẹli Keji 20:7 BM

7 Gbogbo àwọn ọmọ ogun Joabu, ati àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun yòókù, tí wọ́n kù ní Jerusalẹmu bá tẹ̀lé Abiṣai láti lépa Ṣeba.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:7 ni o tọ