Samuẹli Keji 22:18 BM

18 Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi, tí ó lágbára;ati lọ́wọ́ gbogbo àwọn tí wọ́n kórìíra mi;nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 22

Wo Samuẹli Keji 22:18 ni o tọ