14 Dafidi wà ní orí òkè kan tí wọ́n mọ odi yípo, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ ogun Filistini kan ti gba Bẹtilẹhẹmu, wọ́n sì wà níbẹ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23
Wo Samuẹli Keji 23:14 ni o tọ