Samuẹli Keji 23:19 BM

19 Òun ni ó jẹ́ olókìkí jùlọ ninu “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni,” ó sì di aṣiwaju wọn, ṣugbọn kò lókìkí tó “Àwọn Akọni Mẹta” àkọ́kọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:19 ni o tọ