Samuẹli Keji 23:24 BM

24 Àwọn mìíràn tí wọ́n tún jẹ́ ara “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni” náà nìwọ̀nyí: Asaheli arakunrin Joabu, ati Elihanani, ọmọ Dodo, ará Bẹtilẹhẹmu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:24 ni o tọ