33 Ṣama, ará Harari, Ahiamu, ọmọ Ṣarari, ará Harari;
34 Elifeleti, ọmọ Ahasibai, ará Maaka, Eliamu, ọmọ Ahitofẹli, ará Gilo;
35 Hesiro, ará Kamẹli, Paarai, ará Abiti;
36 Igali, ọmọ Natani, ará Soba, Bani, ará Gadi;
37 Seleki, ará Amoni, Naharai, ará Beeroti, tí ó máa ń ru ihamọra Joabu, ọmọ Seruaya.
38 Ira ati Garebu, àwọn mejeeji jẹ́ ará Itiri;
39 ati Uraya, ará Hiti.Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ọmọ ogun náà jẹ́ mẹtadinlogoji.