Samuẹli Keji 24:1 BM

1 Inú tún bí OLUWA sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì ti Dafidi láti kó ìyọnu bá wọn. OLUWA wí fún un pé, lọ ka àwọn ọmọ Israẹli ati ti Juda.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:1 ni o tọ