Samuẹli Keji 24:23 BM

23 Arauna kó gbogbo rẹ̀ fún ọba, ó ní, “Kí OLUWA Ọlọrun rẹ gba ẹbọ náà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:23 ni o tọ