Samuẹli Keji 24:7 BM

7 Lẹ́yìn náà, wọ́n lọ sí apá gúsù. Wọ́n dé ìlú olódi ti Tire, títí lọ dé gbogbo ìlú àwọn ará Hifi, ati ti àwọn ará Kenaani. Níkẹyìn, wọ́n wá sí Beeriṣeba ní apá ìhà gúsù Juda.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 24

Wo Samuẹli Keji 24:7 ni o tọ