Samuẹli Keji 3:19 BM

19 Abineri bá àwọn ará Bẹnjamini sọ̀rọ̀ pẹlu. Lẹ́yìn náà ó lọ bá Dafidi ní Heburoni láti sọ ohun tí àwọn ará Bẹnjamini ati gbogbo ọmọ Israẹli ti gbà láti ṣe fún Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3

Wo Samuẹli Keji 3:19 ni o tọ