30 Bẹ́ẹ̀ ni Joabu ati Abiṣai, arakunrin rẹ̀, ṣe pa Abineri tí wọ́n sì gbẹ̀san ikú Asaheli, arakunrin wọn, tí Abineri pa lójú ogun Gibeoni.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 3
Wo Samuẹli Keji 3:30 ni o tọ