1 Nígbà tí Iṣiboṣẹti ọmọ Saulu gbọ́ pé wọ́n ti pa Abineri ní Heburoni, ẹ̀rù bà á gidigidi, ìdààmú sì bá gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 4
Wo Samuẹli Keji 4:1 ni o tọ