Samuẹli Keji 4:10 BM

10 ẹni tí ó wá ròyìn ikú Saulu fún mi ní Sikilagi rò pé ìròyìn ayọ̀ ni òun mú wá fún mi, ṣugbọn mo ní kí wọn mú un kí wọ́n pa á. Ó jẹ èrè ìròyìn ayọ̀ rẹ̀, tí ó mú wá fún mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 4

Wo Samuẹli Keji 4:10 ni o tọ