Samuẹli Keji 5:23 BM

23 Dafidi tún tọ OLUWA lọ láti bèèrè ohun tí yóo ṣe. OLUWA dá a lóhùn pé, “Má ṣe kọlù wọ́n níhìn-ín, ṣugbọn múra, kí o yípo lọ sẹ́yìn wọn, kí o sì kọlù wọ́n ní apá òdìkejì àwọn igi basamu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 5

Wo Samuẹli Keji 5:23 ni o tọ