Samuẹli Keji 6:11 BM

11 Àpótí ẹ̀rí OLUWA náà wà níbẹ̀ fún oṣù mẹta, OLUWA sì bukun Obedi Edomu ati ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:11 ni o tọ