Samuẹli Keji 7:26 BM

26 Orúkọ rẹ yóo sì lókìkí títí lae, gbogbo eniyan ni yóo sì máa wí títí lae pé, OLUWA àwọn ọmọ ogun ni Ọlọrun Israẹli. O óo sì mú kí arọmọdọmọ mi wà níwájú rẹ títí laelae.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:26 ni o tọ