6 Láti ìgbà tí mo ti gba àwọn ọmọ Israẹli kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti títí di àkókò yìí, n kò fi ìgbà kan gbé inú ilé rí, inú àgọ́ ni mò ń gbé káàkiri.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7
Wo Samuẹli Keji 7:6 ni o tọ