Samuẹli Keji 7:8 BM

8 “Nítorí náà, sọ fún Dafidi iranṣẹ mi pé, ‘Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo mú un kúrò níbi tí ó ti ń ṣọ́ àwọn aguntan, ninu pápá, mo sì fi jọba Israẹli, àwọn eniyan mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:8 ni o tọ