Samuẹli Keji 8:11 BM

11 Dafidi ọba ya àwọn ẹ̀bùn náà sí mímọ́ fún ìlò ninu ilé OLUWA, pẹlu gbogbo fadaka ati wúrà tí ó rí kó láti gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó ti ṣẹgun;

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:11 ni o tọ