Samuẹli Keji 8:13 BM

13 Dafidi túbọ̀ di olókìkí sí i nígbà tí ó pada dé, láti ibi tí ó ti lọ pa ẹgbaasan-an (18,000) ninu àwọn ará Edomu, ní Àfonífojì Iyọ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:13 ni o tọ