15 Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe jọba lórí gbogbo Israẹli, ó sì ń ṣe ẹ̀tọ́ ati òdodo sí gbogbo eniyan, nígbà gbogbo.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8
Wo Samuẹli Keji 8:15 ni o tọ