Samuẹli Keji 8:5 BM

5 Nígbà tí àwọn ará Siria dé láti Damasku tí wọ́n ran Hadadeseri, ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi pa ẹgbaa mọkanla (22,000) ninu àwọn ọmọ ogun wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 8

Wo Samuẹli Keji 8:5 ni o tọ