Samuẹli Keji 9:1 BM

1 Ní ọjọ́ kan, Dafidi bèèrè pé, “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni kù ninu gbogbo ìdílé Saulu tí mo lè ṣoore fún nítorí Jonatani?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 9

Wo Samuẹli Keji 9:1 ni o tọ