Samuẹli Keji 9:4 BM

4 Ọba bi í pé, “Níbo ni ó wà?”Siba dá ọba lóhùn pé, “Ó wà ní ilé Makiri, ọmọ Amieli, ní Lodebari.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 9

Wo Samuẹli Keji 9:4 ni o tọ