Ìṣe Àwọn Aposteli 1:18 BM

18 (Ó ra ilẹ̀ kan pẹlu owó tí ó gbà fún ìwà burúkú rẹ̀, ni ó bá ṣubú lulẹ̀, ikùn rẹ̀ sì bẹ́, gbogbo ìfun rẹ̀ bá tú jáde.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 1:18 ni o tọ