Ìṣe Àwọn Aposteli 1:19 BM

19 Gbogbo àwọn eniyan tí ó ń gbé Jerusalẹmu ni ó mọ̀ nípa èyí. Wọ́n bá ń pe ilẹ̀ náà ní “Akelidama” ní èdè wọn. Ìtumọ̀ èyí ni “Ilẹ̀ Ẹ̀jẹ̀.”)

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 1:19 ni o tọ